Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 890

Jesu so fun won pe.........Emi wa pelu yin Nigba gbogbo, titi o fide opin aye.

Meter: 10.9.10.9 & Ref

Scripture: Mat. 28:20

1

mfOre bi Jesu kosi laye yi,

Oun nikan l’ore otito,

Ore aye yi y’o fi wa sile;

Sugbpn Jesu ko je gbagbe wa.

CHORUS

Ah! ko je gbagbe wa; (2x)

Sugbpn Jesu ko je gbagbe wa.

2

Akoko nkoja lo lai f’ota pe;

A fojo kan sunmole wa si;

Onidajo mbo, gongo yio so;

Awawi kan kosi l’ojo na.

3

Duro d’Oluwa, ma siyemeji

Ohunkohun t’o wu ko le de;

’Gbat’ o ro p’o pin ’ranwo Re y’o de;

Eni ’yanu l’Oba Oluwa.