Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 893

Ibukun ni fun awon ti ngbe inu ile R.

Meter: 6.6.6.6.8.8.

Scripture: OD. 84:4

1

mfKristi n’ipile wa,

Lori Re lao kole,

Awon mimo nikan

L’o ngb’ agbala orun

Ireti wa

T’ore aye,

T’ayo ti mbo

Wa n’nu ’fe Re

2

fAgbala mimo yi

Yo ho f’orin iyin;

A o korin iyin s’l

Metalokan mimo,

Be lao f’orin

Ayo kede

Oruko Re

Titi aye.

3

mfOlorun Olore,

F’iyesimi nihin:

Gba eje t’a mu wa

At’ebe wa gbogbo;

K’O si f’opo

’Bukun dahun

Adura wa

Nigba gbogbo.

4

crNihin je k’ore Re

T’a ntoro lat’ orun

Bo s’ori wa lekan

Ko ma si tun lo mo

diTit’ojona

T’ao s’akojo

pAwon mimo

Sib’isimi.