Hymn 895
Emi o sifi ogo kun ileyi, li Oluwa awon omo ogun wi.
Meter: S.M.
Scripture: Hag. 2:7
1
fOlorun wa tobi,
Eje k’iyin Re po,
O f’ile sin Re se bugbe
At’ibujoko Re
2
fTempili or’ofe,
A! won ti dara to!
Awon li ola ilu wa
At’odi ile wa.
3
crNi Sion, Olorun
L’abo n’igba ’ponju
ffIgbala Re ti logo to
N’nu awon afin Re!
4
mpBi iponju bade,
crA o lo si’le Re;
diA o ranti ore-ofe Re,
Ao wa ’gbala nibe.