Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 90

Emi o si fi Ota sarin iwo ati obirin na, ati sarin iru-Omo re ati iru-Omo re. On o foo li ori, iwo yio si pa a ni gigise

Meter: C.M

Scripture: Gen. 3:15.

1

fIyin f Eni mimo julo

L’oke ati ni ‘le;

Oro Re gbogbo je ’yanu,

Gbogb’ ona Re daju.

2

mfOgbon Olorun ti po to

p’Gbat’ eniyan subu;

crAdam’ keji wa s’oju ’ja .

fAti lati gbala.

3

mfOgbon ife! p’eran ara

pT’o gbe Adam’ subu

crTun b’ota ja ija otun

fK’o ja, k’o si s’egun.

4

mfAti p’ebun t’o j’or-ofe

So ara di otun

pOlorun papa tikare

J’Olorun ninu wa.

5

mfIfe ’yanu! ti Eni ti

O pa ota eniyan

Ninu awo awa eniyan

Je irora f’eniyan.

6

pNikoko, ninu ogba ni

Ati l’ori igi

crT’o si ko wa lati jiya

pT’o ko wa lati ku.

7

fIyin f’Eni mimo julo

L’oke ati nile

Oro Re gbogbo je ’yanu

Gbogb’ ona Re daju.