Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 902

Nitori ile adura li a o ma pe ile mi fun gbogbo eniyan.

Meter: 8.7.8.7.4.7.

Scripture: Isa. 56:7

1

fOlorun Baba, Ologo,

T’O joko lor’ite lae

Awa omo Re teriba.

A nw’ojure Re nikan;

ffOluwa wa,

pJek’anu Re han si wa.

2

fOlorun Omo ’Lugbala,

T’O duro n’ite anu,

O ti jeje ojure Re

Nibit’ eeyan Re ba pe;

ffAlabukun,

pBukun wab’ati duro.

3

fOlorun emi, to nwe ni,

’Mole, Iye, Agbara,

OWO ina mimo loke,

Mu k’oju Re dan si wa

ffEmi Mimo,

S ago yi ni Tire.

4

fBaba, Omo, ati Emi,

Ife’sokan, so kale;

Ki ore-ofe Re si wa

SO ile yi di Tire;

ffJehofa nla,

Ran ogo ’dahun si wa.