Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 906

E LO wasu ihinrere fun gbogbo eda.

Meter: 11.10.11.10.11.10.

Scripture: Mk. 16:15

1

mfYo awon ti nsegbe, sajo eni nku,

crF’anu ja won kuro ninu ese;

Ke f’awon ti nsina gb’eni subu ro,

So fun won pe, Jesu le gba won la

CHORUS

pYo awon ti nsegbe, sajo eni nku,

crAlanu ni Jesu, yio gbala.

2

mfBi won tile gan, sibe O nduro

Lati gb’omo t’o ronupiwada

pSa fitara ro won, si ro won jeje,

On o dariji bi won je gbagbo.

3

mfEro okan eda ti esu te pa

Ni ore-ofe le tun mu pada;

Okan ti o gb’ogbe, t’a fowo ife

At’inu rere soji, y’o korin.

4

Yo awon ti nsegbe - ise tire ni,

Oluwa yio f’agbara fun o;

Fi suru ro won pada s’ona toro,

So f’asako p’Olugbala ti ku.