Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 908

E si kiyesi, Emi wa pelu yin Nigbagbogbo titi o fi de opin aye

Meter: L.M

Scripture: Mat 28:20

1

mf‘Gbati Jesu g’oke r’orun

N’isegun lori ota Re;

O tu ebun sori aye,

Ore Re si tan kakiri

2

crNibe l’Aposteli ti dide,

Mimo won tayo okiki

Bi won l’awon eni rele

Ti ns’alufa at’oluko

3

fKristi l’orisun ebun won

On ni iye or’ofe won

B’o ti nf’owo Re gbe won ro

Won duro sinsin n’un ‘ponju

4

crBe n’iran won ki o dase

Titi aye yo fi dopin;

Nipa won ni Ijo titun

Yo dide, y’o si ma gbile

5

fJesu, je ki okan wa mo

Orisun ibukun wonyi;

K’alufa at’ijo yin O,

Tit’aye anipekun