Hymn 912
Won tete ko fi awon tikarawon fun Oluwa.
Meter: L.M
Scripture: II Kor 8:5
1
K’emi n’tori eru eniyan
Da se Emi druo n’nu mi?
Tabi ki njeri f’Oluwa
L’oro on ise, laifoya?
2
Ifajuro eniyan le
Mu mi pa or’Olorun mo?
diBawo l’emi y’o ti se le
Duro loju ibinu Re?
3
crK’emi ha din oro Re ku,
K’o le ba ti aye lara;
Tabi, ki nsa f’agbelebu,
Ki nle jere ohun aye?
4
mpOlugbala, oju Re ri
Gbogbo ero ‘nu okan mi;
pOhun kan ha gba mi laya
Faji aye tab’iyin re?
5
mfIfe Krist ni o nro mi
Lati wa emi t’o sako;
mpKi nfi ebe ati ekun
Ja won l’enu isa oku
6
mpMo m’emi atara mi wa
Bi won le wulo f’oto Re;
crMu imo Re se, Oluwa;
K’a se ‘fe Re, k’a juba Re,
7
mfFun mi l’agbara, Olorun;
Iji ba ja, ara ‘ba san,
Eleri ooto ni un o je
Mo le s’ohun gbogbo n’nu Re.