Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 913

Sugbon nitori oro re, emi o ju awon Na si isale

Meter: S.M

Scripture: Lk. 5:5

1

Jesu, b’a nfurugbin,

Oro ‘ye lase Re;

B’a ti owo Re b’omirin,

‘Rugbin na y’o dagba

2

mfIpa or’ofe Re

Y’o mu bisi pupo;

Y’o so oloto di pupo

Ti nwa fun ogo Re

3

mfRo ojo ibukun

Ti ihin rere Re,

K’agbara ti ny’okan pada

Ba iran Re gbe

4

crFun opo eniyan

N’ife isodotun;

F’ayo or’ofe pese won

F’ayo kikun loke