Hymn 922
E gba awon ti nse olori yin gbo, ki e sifi ori yin bale, nitori won nso eso nitori okan yin.
Meter: L.M.
Scripture: Heb. 13:17.
1
mfOwo l’eni ororo Re,
L’ojise oro mimo Re
Ipo eni owo l’o wa.
Jek’ a f’iyin at’ola fun.
2
Ipo elege n’ipo re,
ASO ti ko fe abawon.
Jek’ a fi ife ran lowo,
K’a fi irele gb'oro re.
3
Niwon b’o ti wu O lati
Fi oluso emi wa,
pFun ni suru lati to wa,
Ati opo if’ara da.
4
mpMa jek’ise wa mu binu,
Ki iwawa tan ni suru;
Fun l'agbara bi ojo re,
B’ipo re, fun lor' ofe Re.
5
mpJek’ a r’ewa Re lara re,
K’o ma ran n’nu iwa pele,
K’o mo ’po re bi oluso,
K’a mo ti wa b’agutan re