Hymn 93
E fi ogo fun Oluwa.
Meter: 11.11.11.11. & Ref.
Scripture: OD. 29:2.
1
f'O go ni f’Oluwa to se ohun nla
Ife lo mu k’O fun wa ni OmO Re,
Enit’O f’emi Re le ‘le f’ese wa
To si silekun iye sile fun wa.
CHORUS
ffYin Oluwa, Yin Oluwa,
F’ iyin fun Oluwa,
ffYin Oluwa, Yin Oluwa,
E YO niwaju Re,
Ka to Baba wa LO l’Oruko Jesu,
Je k’ a JO f’ogo fun Onise-’yanu.
2
fIrapada kikun ti eje Re ra
F’enikeni t’o gba ileri Re gbo,
Enit’o buruju b’o ba le gbagbo,
Lojukanna y’o ri idariji gba.
3
fO s’ohun nla fun wa, O da wa l’ola
Ayo wa di kikun ninu Omo Re
Ogo ati ewa irapada yi
Y’o ya wa lenu ‘gbat’ a ba ri Jesu