Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 937

Won wo inu alafia; Won simi lori akete won.

Meter: L.M

Scripture: Isa. 57:2.

1

mpIgba asale ti dun to,

Ti ara tu ohun gbogbo,

’Gbati itansan orun ale

Ba ntan mole s’ohun gbogbo!

2

Beni ’keyin onigbagbo,

On a simi l’alafia;

crlgbagbo t’o gbona janjan,

A mole ninu okan re.

3

mpImole kan mo l’oju Re,

Erin si be ni enu re;

O nfede t’ahon wa ko mo,

Soro ogo t’o sunmo ’le.

4

crltansan’mole t’orun wa

Lati gba ni ’yanju l’ona

Awon angel duro yi ka

Lati gbe lo s’ibugbe won

5

mpOluwa, je k’a lo bayi,

K’a ba O yo, k’a r’oju Re;

Te aworan Re s’okan wa

Si ko wa b’a ti ba O rin.