Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 938

Li owo Re ni mo fi emi mi le.

Meter: 7.7.7.7.

Scripture: OD. 31:5.

1

mpLala alagba se tan;

Ojo ogun ti pari;

crL’ebute jinjin rere

Ni oko re ti gun si,

Baba l’abe itoju Re,

L’awa f’iranse Re yi si.

2

mfN’ibe l’are won l’ekun

Nibe, won m’ohun gbogbo

diOnidajo ododo

Ndan se aye wo nibe.

3

mfNibe l’Olus’agutan

Nko awon agutan lo,

diNibe l’o ndabobo won,

Koriko ko le de ’be.

4

mpNibe l’awon elese,

Ti nteju m’agbelebu

crY’o mo ife Kristi tan

L’ese Re ni Paradise

5

mfNibe l’agbara Esu,

Ko le b’ayo won je mo

Kristi Jesu sa nso nwon

On t’o lu fun’dande won.

6

pp“Erupe fun erupe’’

L’ede wa, nisisiyi;

A te sile lati sun

crTiti d’ojo ajinde.