Hymn 943
Goke Jordani.
Meter: 7.6.7.7.6.
Scripture: Jos. 3:17
mfA! won ti gun s’ebute,
pLoke orun; Loke orun;
mfEbi ko ni pa won mo,
Won bo lowo irora
fLoke orun; Loke orun.
A! Won ko wa fitila,
pLoke orun; Loke orun;
’Mole ni l’ojo gbogbo,
Jesu si n’Imole won,
fLoke orun; Loke orun.
A! Wura n’ita won je,
pLoke orun; Loke orun;
Ogo ’be si po pupo,
Agbo Jesu ni won je
fLoke orun; Loke orun.
A! Otutu ki mu won,
pLoke orun; Loke orun;
Owore won ti koja,
Gbogbo ojo l’o dara;
fLoke orun; Loke orun.
A! won dekun ija ’ja,
pLoke orun; Loke o1run;
Jesu l’o ti gba won la,
T’awon Tire l’o si nrin,
Loke orun; Loke orun.
A! won ko ni sokun mo,
pLoke orun; Loke orun;
Jesu sa wa lodo won,
Lodo Re ni ayo wa,
fLoke orun; Loke orun.
A! A o dapo mo won,
pLoke orun; Loke orun;
A nreti akoko wa,
f’Gba Oluwa ba pe ni
diS’oke orun; S’oke orun.