Hymn 946
Sisun li osun.
Meter: S.M.
Scripture: Lk. 8:52
1
mfO sun, ni Jesu wi
Nipa ti Lasaru
Eni t’O ku, ti a ti sin,
T’ati te s’iboji.
2
diOku ojo merin
Sun ni, loju Jesu;
crOn l’ Ajinde ati Iye
Fun awon t’o gba gbo
3
mfOre Jesu ki ku,
Won a ma parada,
Kuro ni kokoro ile
S’ohun ti nfo l’oke.
4
diSun, ara, olufe,
Jesu duro ti o,
crMa foya, O ti s’eleri
Ajinde f’eni Re.
5
mfO fere gb’ohun na,
Lat’ oju orun re,
Ohun didun Jesu ti y’
Pe o si ajinde.
6
crA ko ni baraje
Bi alainireti,
Od’owuro l’a o ki o.
Sun re, ara, sun re.
7
mpAwa pelu y’o sun
Li akoko tiwa:
crA! k’ile mo ba gbogbo wa
L’ese Olugbala.