Hymn 948
Awon emi, nipa igbagbo ati suru, li o jogun ileri wonni.
Meter: S.M.
Scripture: Heb. 6:12
1
mfF’awon eniyan Re,
T’o ti Faye sile;
Awon t’o mo O, to sin O,
Gba orin iyin wa.
2
mfF’awon eniyan Re,
Gba ohun ope wa;
Awon t’o fi O s’esan won,
Won ku n’igbagbo Re.
3
mfNi gbogbo aye won
’Wo ni won nwo loju;
Emi Mimo Re l’o nko won
Lati s’ohun gbogbo.
4
fFun eyi, Oluwa
crA nyin oruko Re;
Je k’a ma tele iwa won,
diKi a le ku bi won.