Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 949

A fi awosanma fi eri pupo yi wa ka

Meter: 10.10.10.4.

Scripture: Heb. 12:1

1

mfF’awon eniyan Re t’o lo simi;

Awon ti o fi ’gbagbo jewo Re,

fK’a yin oruko Re; Olugbala

Aleluya!

2

Iwo l’apata won at’odi won,

IWO ni Balogun won l’oju ’ja,

crIWO ni imole okunkun won

Aleluya!

3

mpJe ki awon om’ogun Re l’aye

crJagun nitoto b’awon ti ’gbani;

fKi won le gba ade ogo bi won

Aleluya!

4

mfIdapo ibukun wo lo to yi,

crAwa nja n’ihin, awon nyo

fBe tire kanna l’awa at’awon – Aleluya!

5

mf’Gbat’ ija ba ngbona, ti ogun nle,

pA dabi eni ngb’orin ayo won;

crIgboya a si de, at’agbara Aleluya!

6

pOjo nlo, orun wa fere wo na,

Awon ajagun toto y’o simi.

Didun ni isimi paradise-Aleluya!

7

fLeyin eyi, ojo ayo kan mbo,

Awon mimo y’o dide n’nu ogo;

Oba ogo yio wa larin won-Aleluya!

8

ffLat’opin ile lat’opin okun,

Ogunlogo nro wo ’bode Pearli;

Won nyin Baba, Omo ati Emi-Aleluya!