Hymn 952
Olorun yio si nu omije gbogbo nu kuro li oju won.
Meter: 8.7.8.7.
Scripture: Ifi. 21:4
1
mfIbanuje ko si l’orun,
Beni ko si ipinya
crFun awon ta ti dariji;
Ekun ki y’o si l’orun.
Ibanuje ko si ni ’lu na,
Beni ailera ko si,
f’Tori gbogbo ilu naje imole
’Tori ekun ko si l’orun.
2
mfAisedede ko si nibe,
Ko s’oju t’o n’omije
’Tori itelorun y’o wa;
Ekun ki y’o si l’orun
3
crKo si ’robinuje l’oke,
Ko si si imi-edun;
A ki y’o s’oro kikoro,
4
diEkun ki y’o si l’orun.
’Banuje kun okan nihin,
’Tori ipinya ti mbe;
Sugbon ayo l’o wa l’ohun,
Ekun ki y’o si l’orun.