Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 953

Nitori ipeyo dun, a o siji awon oku dide.

Meter: 15.11.15.11.& Ref.

Scripture: I Kor. 15:52

1

mfGbati ipe Oluwa ba dun, t’aye y’o si fo Lo,

Ti imole Ojo titun y’o si de;

Nigbati awon omo igbala ba pejo l’oke,

T’a ba si p’oruko nibe, uno wa m’be,

CHORUS

f’Gbat’ a ba p’oruko l’ohun,

’Gbat’ a ba p’oruko l’ohun,

’Gbat’ a ba p’oruko l’ohun,

crNipa ore-ofe nikan, un o wa n’be.

2

mfL’oro ojo na t’awon oku n’nu Kristi y’o jinde,

Ti won y’o si pin n’nu ogo ajinde;

’Gbati awon ayanfe y’o peji si ode orun,

T’a ba si p’oruko l’ohun, un o wa n’be.

3

crJeki a fi gbogbo akoko wa sise f’Oluwa

Jeki a royin ife iyanu Re;

Nigbati a ba si pari ire ije wa l’aye,

mfT’a'ba si p’oruko l’ohun, un o wa n’be.