Hymn 955
O sifi orin titun si mi li enu, ani orin iyin si Olorun wa.
Meter: 15.15.15.15. & Ref.
Scripture: OD. 40:3
fOrin mbe li orun, iru eyiti awa ko mo,
Nibiti awon angeli nkorin ’yin s’Odagutan
Harpu won ni ohun didun, ohun won si dun pelu,
A! ki awa le se ’bi ti won lati sin Oluwa,
ffMimo, Mimo l’awon angeli nko,
Mo si ni ’reti lati ba won korin li orun,
crSugbon won ko leba mi korin ti irapada
N’tori angeli ko mo ayo ti ’gbala mu wa.
mfSugbon mo gbo orin miran ti a ko l’ohun oke
Si eni t’O ra wa pada t’O si gba wa, l’orin na;
fAwa ti la iponju wa ja si ile didan yi,
Nibi orisun ’ye ti nsan l’O ti fo aso wa mo
diAwon angeli dake, n’tori won ko le korin na,
fBi iro omi pupo l’enu awon t’a f’eje ra!
N’tori won nso ti isegun lori ’danwo at’ija”.
ffWon si nyin Olurapada ti O ti wipe, “O seun”.
fBi emi ko tile nse angeli, mo mo pe l’ohun
Un o b’awon mimo korin t’awon angeli ko ni ko:
ffUn o korin ti Olugbala ti O ku ni Kalfari
Lati dari ese mi ji mi, lati da mi sile.