Hymn 96
Oluwa jOba: O joko larin a won Kerubu.
Meter: 8.7.8.7.4.7.
Scripture: OD. 99:1.
mpOlorun Oluwa l’Oba
crAye mbe niwaju Re:
Nibi t’awon angel’ nsin I,
L’O gunwa ni ite Re
Eni mimo;
Obangiji, On l’Oba.
fOba ogo li Olorun,
Sion, royin Re k’aye;
Isra-eli ti igbani,
Kede itan oto Re:
Eni mimo,
Mimo li oruko Re.
Li atijo, ni ’gba ewu
T’awon ojise Re be,
O gbo ’gbe awon eniyan Re,
N’nu eru Won, O dahun,
Eni mimo;
Won ri n’tosi’gba won p’E.
mfAwon l’afun 1’ofin mimo
Lat’ inu awosanma;
Ilana mimo ti won ru,
pMu ki O binu si won:
Eni mimo;
Won kanu fun ese won.
crSugbon Baba won fiji won,
’Gba won tun saferi Re
mfO mura tan lati gba won
fO f’ife gba won pada:
Eni mimo;
mfAwa na nw’ or’-ofe Re.
Baba wa n’iyonu n’nu Krist’,
Y’o mu ileri e? se:
fWa, k’a gbe ga, gbogb’alaye;
E wa soke mimo Re!
Eni mimo;
E sin loke mimo Re