Hymn 961
A wa ti ni Olori Alufa nla kan ti o ti Koja lo sinu awon orun.
Meter: L.M.
Scripture: Heb. 4:14
1
fOlor’ Alufa giga kan,
T’o gb’eda wa WO f’ara han
Nibi ti tempil orun wa,
Ile ti a ko f’owo ko.
2
pOn bi Onigbowo eniyan
T’o t’eje ’yebiye s’ile
T’o npari 'se nla Re l'orun;
Olugbala, Ore eniyan
3
mfB’o tile g’oke lo s'orun
O nf’oju ife wo aye
Eni t’Oje oko eniyan
O mo ailera eda wa.
4
mpAlabajiya wa si mo
Bi ’rora wa si ti po to,
diL’orun, O si ranti sibe
ppOmije on ’waya ‘ja Re
5
mpNinu ibanuje okan,
Eni ’banuje pin n’nu Re
crO mba wa daro edun wa
O si nran ojiya lowo
6
fK’a k’edun wa lo s’odo Re
Pelu ’gboya, nibi ite
K’a toro agbara orun;
Lati yo wa nigba ibi