Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 963

Sugbon nisisiyi won nfe ilu kan ti O dara ju belo.

Meter: 6.6.6.6.8.8.

Scripture: Heb. 11:16

1

mfJerusalem’ t’orun

L’orin mi, ilu mi!

Ile mi bi mba ku;

Ekun ibukun mi;

Ibi ayo!

Nigbawo ni

U n o r’oju Re

Olorun mi?

2

mfNibe l’Oba mi wa,

pT’a da l’ebi l’aye;

fAngeli nkorin fun,

Won si nteriba fun.

3

Patriark igbani,

Par’ayo won nibe

Awon woli, won nwo,

Omo Alade won!

4

mfNibe ni mo le ri

Awon Aposteli;

At’awon akorin

Ti nlu harpu wura

5

mpNi agbala wonni,

Ni awon Martir wa;

crWon wo aso ala,

Ogo bo ogbe won.

6

pT’emi yi sa su mi,

Ti mo ngb’ago Kedar;

Ko si ’ru yi loke,

Nibe ni mo fe lo