Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 967

Nitori ti o pese ilu kan sile fun won

Meter: 8.9.8.H.

Scripture: Heb. 11:16

1

mfA nsoro ile ’bukun ni,

Ile didan at’ile ewa;

’Gbagbogbo l’a nso t’ogo re

pY’o ti dun to lati de be!

2

mfA nsoro ita wura Re;

Oso odi re ti ko l’egbe

’Faji re ko se f’enu so;

pY’o ti dun to lati de'be!

3

fA nso p’ese ko si nibe!

Ko s’aniyan at’ibanuje,

Pelu 'danwo l'ode, ninu;

pY’o ti dun to lati de ‘be!

4

fA nsoro orin Iyin re.

Ti a kole l’orin aye we,

diB’o ti wu k'orin wa dun to

pY’o ti dun to lati de’be!

5

fA nsoro isin ife re

Ti agbada t’awon mimo nwo,

Ijo akobi ti oke;

pY’o ti dun to lati de’be

6

mpOluwa l’onakona,

Sa se emi wa ye fun orun:

crLaipe awa na yio mo

B’o ti dun to lati de ’be.