Hymn 969
A wa nyo ni ireti ogo Olorun.
Meter: 8.8.6.D.
Scripture: Rom. 5:2
1
mpLeyin aye buburu yi,
pAye ekun on osi yi,
Ibi rere kan wa;
Ayipada ko si nibe,
Ko s’oru, a f’osan titi,
pWi mi, ’wo o wa nibe?
2
mf’Lekun ogo re ti m’ese,
Ohun eri ko le wo ’be,
Lati b’ewa re je;
fL’ebute daradara ni,
A ko ni gburo egun mo.
Wi mi, ’wo o wa nibe
3
fTan’ y’o de ’be? Onirele,
T’o f’iberu sin Oluwa,
T’won ko naani aye:
Awon t’a f’Emi mimo to
Awon t’o nrin l’ona tooro,
fAwon ni o wa nibe.