Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 970

Ile rere na ti mbe loke Jordani.

Meter: 8.9.9.9. & Ref.

Scripture: Deut. 3:25

1

mfA! Ro ti ibugbe orun,

Li eba odo ti imole,

Nibit’ awon mimo wa laiku

Ti a wo won li aso funfun,

CHORUS

Lok’orun! lok’orun!

Lok’orun! lok’orun!

A! ro ti ibugbe orun

2

mfA! ro t’awon ore nibe,

Awon ti o ti lo saju wa

Ati awon orin ti won nko

N’ile won ni afin Olorun

3

Olugbala mi wa nibe,

N’be l’awon ibatan mi nsimi,

Je ki nfi ’banuje s’apakan

Ki nsi fo lo s’ile abukun.

4

mfMo fere de ibugbe na,

Nitori mo r’opin ajo mi,

Opo l’awon ti okan mi nfe

Won ns’ona, won si duro demi