Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 971

Nitori Odo-Agutan ti mbe larin ite na ni yio si ma se amona won si ibi orisun omi iye.

Meter: 8.6.8.6.7.7.7.6.

Scripture: lfi. 7:17

1

mfA o pade ’oke odo,

Nigbose, nigbose,

Okunkun y’o si rekoja

Nigbose, nigbose,

cr’Gbati ajo ba pari,

T’a si segun t’o logo.

A o si ma ran bi orun

Nigbose, nigbose.

2

fA o ma lu harpu ogo

Nigbose, nigbose.

A o ma korin irapada,

Nigbose, nigbose

crTiti lae li orin na

Y’o ma f’adun ro yi ka

Ebute ayeraye,

Nigbose, nigbose.

3

fAwa y’o si dabi Jesu,

Nigbose, nigbose

Ti y’o fun wa l’ade iye,

Nigbose, nigbose

crAwon angeli pelu

Ti nmu gbogbo ’fe Re se

Won y’o ma se ike wa

Nigbose, nigbose.

4

fOmije oju wa y’o gbe,

Nigbose, nigbose,

Pelu ayo nla l’ao si mo,

Nigbose nigbose,

diAwon mimo,t’o saju

Lo si ile ayo na,

Pe l’ayo lao tun dapo

Nigbose, nigbose.