Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 972

Okan mi nfa nitoto fun agbala Oluwa.

Meter: 6.6.6.6.8.8.

Scripture: OD. 84:2

1

mfOluwa wa orun!

Ago Re l’aye yi,

Ibugbe ife Re,

Ewa Re ti po to!

ffOkan mi n fa s’ibugbe Re,

O ns'aferi Olorun mi

2

mfAyo b’awon ti n sin,

Nibit’ Olorun yan,

Ti nwon npara ibe

Lati ma josin won

ffWon nyin O sa; ayo b’awon

T’o fe ona oke Sion

3

fLati ipa de’pa

L’aye osi wa yi;

Titi won fi goke,

Ti won si yo s’orun

ff’Bugbe Ogo! ’gba t’ Olorun

Bam’ese wa de ibe na.

4

mfOlorun l’asa wa,

Imole at’odi.

Owo re kun f’ebun

A ngba ’bukun nibe

ffOun y’o febun Ore-ofe

Ati ogo fun iran wa.