Hymn 973
Isimi kan ku fun awon eniyan Olorun
Meter: 10.10.10.10.
Scripture: Heb. 4:9
mfKini ’simi ayo; ailopin ni
T’awon angel at’awon mimo ni?
mp’Simi f’alare, f’awon asegun,
fNibe l’Olorun je ohun gbogbo
mfTal’Oba na, tani yi ’te Re ka?
pIrora itura Re ha ti ri?
mfSo fun ni, eyin ti njosin nibe
B’ahon le so titobi ayo na
Jerusalem toto ilu mimo,
T’alafia re j’ayo ailopin,
Ar’ohun t’a nfe n’nu re, ka to wi,
A si rigba ju eyit’ a nfe lo
L’agbara Oba wa, wahala tan,
Laiberu, l’a o ma korin Sion
Oluwa; niwaju Re, l’ao ma fi
Idahun ’fe han f’ebun ife Re
cr'Simi ko le tele, ’simi nibe
Enikan ni ’simi ti nw’ oju re,
fNibe, orin Jubeli ko le tan;
mpT’awon mimo at’angeli y’o ko.
crL’aye yi, pelu ’gbagbo at’adua
L’ao ma s’aferi ’le Baba orun
fBi igbekun ti nti Babiloni
mpPada lo si ilu Jerusalem.
pNisiyi, a wole niwaju Re.
crTi Eni ti ohun gbogbo ise
mfNinu eni ti Baba at’Omo
Ati Emi je okansoso.