Hymn 977
A won Ologbon yio si ma tan bi imole ofurufu.
Meter: 8.7.8.7.7.7.
Scripture: Dan. 12:3
1
fTal’awon wonyi b’irawo
Niwaju ite mimo,
Ti won si de ade wura,
Egbe ogo wo l’eyi?
ffGbo won nko Aleluya!
Orin iyin Oba won.
2
mfTali awon ti nko’ mana
T’a wo l’aso ododo?
Awon ti aso funfun won
Yio ma funfun laelae,
Beni ki y’o gbo laelae,
Nibo l’egbe yi ti wa?
3
pAwon wonyi l’o ti jagun
F’ola Olugbala won;
Won jijakadi tit’iku,
Won ki b’elese k’egbe
crWonyi ni ko sa f’ogun,
fWon segun nipa Kristi.
4
pWonyi lokan won ti gbogbe
Ninu ’danwo kikoro
Wonyi li o ti f’adura
Mu Olorun gbo ti won;
crNisisiyi won segun;
Olorun re won l’ekun.
5
mfAwon wonyi l’o ti wa,
Ti won file won fun Krist’;
Won si y’ara won si mimo
Lati sin nigbagbogbo;
Nisisiyi li orun,
Won wa l’ayo l’odo Re