Hymn 978
Idile kan li orun ati li aiye.
Meter: C.M.
Scripture: Efe. 3:15
1
fWa, k’a da m’awon ore wa
Ti won ti jere na;
N’ife k’a f’okan ba won lo
S’ode orun l’ohun.
2
K’awon t’aye, d’orin won mo
T’awon t’o lo s’ogo,
Awa l’aye, awon l’orun
Okan ni gbogbo wa.
3
mpIdile kan n’nu Krist’, ni wa,
Ijo kan l’a si je;
diIsan omi kan l’o ya wa!
pIsan omi iku
4
fEgbe ogun kan t’Olorun,
Ase Re l’a si nse;
mpApakan ti wo ‘do na ja,
Apakan nwo lowo!
5
crEmi wa fere dapo na,
Y’o gb’ade bi ti won;
fA o yo s’ami Balogun wa
Lati gbo ipe Re
6
crJesu, so wa, s’amona wa
‘Gbat’ oniko ba de
fOluwa pin omi meji,
Mu wa gunle l’ayo