Hymn 98
Kili emi o san fun Oluwa nitori gbogbo ore Re si mi.
Meter: C.M.
Scripture: OD. 116:12.
1
mfKini un o fun Olorun mi
Fun gbogbo anu Re?
Un o gba ebun Re, un o si fi
Irele bere si.
2
crAgo or’-ofe igbala
L’emi o f’ope gba,
Un o feyinti iieri Re,
Uno si wa f’ogo Re.
3
mfLoju awon eniyan Re
Ni un o san eje mi,
Uno f’ara mi on ini mi
Fi josin f’Olorun.
4
mpBaba, gbogb’ ohun ti mo ni
’Wo l’o fijinki mi;
Mo je omp Re laye yi,
’Wo si ra mi pada.
5
Owo Re l’o da mi, lo si
Da mi n’de n’nu ese;
Anu Re t’o tu ide mi
Si ti de mi mo O
6
fOlorun Olodumare mi,
Uno ma kokiki Re,
Enu y’o ru ebo iyin,
Un o kepe oko Re.
7
ffE f’iyin f’OIorun ife
T'o f’ese mi ji mi,
Titi ao pelu ’jo toke
Ko orin ti orun.