Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 980

Angeli Oluwa wipe lo so gbogbo oro ipe yi.

Meter: 11.10.11.10.9.11.

Scripture: Ise A. 5:20

1

mfGbo, okan mi, bi angeli ti nkorin

Yika orun ati yika aye;

E gbo bi oro orin won ti dun to!

Ti nso’gbati ese ki o si mo;

CHORUS

pAngeli Jesu, angel’ ’mole,

Won nkorin ayo pade ero l’ona,

2

fB’asi ti nlo, be l’a si n gbo orin won:

pWa, alare, Jesu l’o ni k’e wa:

crL’okunkun ni a ngbo orin didun won

mpOhun orin won ni f’ona han wa.

3

pOhun Jesu ni a ngbo l’ona rere,

Ohun na ndun b’agogo y’aye ka;

crEgbegberun awon t’o gbo ni si mbo,

Mu won w’odo Re, Olugbala wa.

4

mfIsimi de, bi wahala tile po,

Ile y’o mo, l’eyin okun aye;

crIrin ajo pari f’awpn alare,

Won o d’orun ’bi ’simi nikeyin.

5

fMa korin nso, eyin angeli rere,

E ma korin didun k’a ba ma gbo

crTit’ao fi nu omije oju wa nu

Ti a o si ma yo titi laelae.