Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 988

Iwo si ti if eje Re si irapada Eniyan si Olorun lati inu eya gbogbo.

Meter: 7.6.8.6.D.

Scripture: Ifi 1:9

1

mfEgbegberun aimoye,

Won wo aso ala;

Ogun awon t’a rapada

Won kun ’bi ’mole na;

fIja won pelu ese

At’iku ti pari;

E s’ilekun wura sile

Fun awon asegun.

2

ffIro Aleluya won

Lo gb’aye, orun kan;

Iro egbegberun harpu

Ndun pe segun de tan;

Ojo t’as’eda aye,

T’a da orile ede,

Ayo nla pa ’banuje re

Ti a fun ni kikun.

3

fA! ayo t’a ko le so

Leti bebe Kenan’:

Idapo nla wo lo to’yi,

Ibi t’a ki npinya;

Oju to kun fekun ri

Y’o tan ’mole ayo;

Ki y’o si alaini baba,

Opo ki y’o si mo.

4

Mu ’gbala nla Re fun wa,

Od’agutan t’apa

Ko ’ruko awon ayanfe,

Mu’pa Re k’o joba;

Wa ife orile ede,

Da onde Re sile;

Wa fi ami ’leri Re han

Wa, Olugbala wa.