Hymn 990
Won si segun re nipa eje Odo-agutan Na ati nitori oro won
Meter: C.M
Scripture: Ifi 12:11
1
mfMba le f’iye igbagbo fo
Wo inu ikele,
Ki nri ayo awon mimo,
B’ogo won ti po to
2
crMo bi won, bi won se segun;
Won f’ohun kan wipe,
Agbara, Od’agutan ni
Iku Re l’ayo won
3
Won kiyesi ipase Re,
Itara Re mu won;
Nipa gbigbo t’Oluwa won,
Won jogun isimi
4
fO to k’a yin Amona wa,
F’apere t’ o fun wa
Bi opo awon eleri
Ti nf’ona orun han.