Hymn 991
Nwon simi kuro ninu lala won.
Meter: 8.8.8.D
Scripture: Ifi 14:13
1
mfAwon mimo, lala pari
Won ti ja, won si ti segun
Won ko fe ohun ija mo
Won da won ‘le l’ese Jesu
crA! Eyin eni ibukun
pIsimi yin ti daju to!
2
mfAwon mimo, irin pari
Won to kun sure ije mo
Are at’isubu d’opin
Ota on eru ko ri mo
crA! Eyin eni ibukun
pIsimi yin ha ti dun to!
3
mfAwon mimo, ajo pari,
Won ti gun sile ibukun
Iji ko d’eru ba won mo,
Igbi omi ko nipa mo
crA! Eyin eni ibukun
pE nsimi n’ibi alafia
4
Awon mimo, oku won sun
Ninu ile, awon nsona,
crTiti won yoo fi jinde
Lati fi ayo goke lo!
fA! eni ‘bukun, e korin
Oluwa at’Oba yin mbo
5
mfOlorun won, ‘Wo l’a nke pe,
Jesu, bebe fun wa l’oke
Emi mimo, Oluto wa
pF’ore-ofe fun wa d’opin
crK’a le b’awon mimo simi
Ni paradise pelu Re.