Hymn 992
Matha gba a sile re Maria si gbo oro Re
Scripture: Luk. 10:38 & 39
1
fFun wa ni 'le Kristian
Ile ti a nkeko Bibelt
Ile ti a nlepa ’fe baba
‘Lati 'fe Re F’ewa de lade
CHORUS
pOlorun Baba wa
Fun wa n'ile Kristian.
2
fFun wa ni 'le Kristian
Nibiti bale je oloto
Ile to bo lowo asise
Ile ti nyo fun ‘fe at' orin
3
fFun wa ni 'le Kristian
Nibi t’iya ile b'ayaba
Nfihan p'ona Re lo dara ju
Ile t'a gb'Olugbala l'aye
4
fFun wa ni 'le Kristian
Nibiti anto awon 'mode
Lati mo Kristi to feran won
Ile ti a ntanna adura