Hymnize

CAC Hymn Collection

Hymn 998

Nigbana li a o si gba awa ti o wa laye ti o si ku lehin soke pelu won sinu awonsanma

Scripture: Thess. 4:17

1

fEje k’a korin ti y'o da wa laraya

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le

Ile y’o su a o si ji si ayeraye

Ko ni pe mo ti a o fi de 'le.

CHORUS

mpLaipe ao de ’le, laipe ao de 'le

T'awa ti Balogun wa

Ao segun iku, ao pade lai pinya mo

Ko ni pe mo ti ao fi de ’le

2

fJek’a gbiyanju k’a sise tokan –tokan

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le

Ore ofe Re o s'agbara wa d'otun

Ko ni po mo ti ao fi d'le

3

E je k'a ran awon alailera lowo

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le

K’a fi ife f’awon asako s’odo Re

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le

4

fIsimi daju a o bo lowo aniyan

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le

Ko si ekun l'ebute daradara na

Ko ni pe mo ti ao fi de 'le