CAC Yoruba Various Hymns
50 various hymns in yoruba.
50 hymns found
Various Hymns
- 1.Bùkún 'lé wa àt'ẹbí wa, àt'ara wa
- 2.Èmi y'ó gbàdúrà s'Ọba mi, Èdùmàrè
- 3.Ọkàn mi yin Olúwa lógo
- 4.Baba, a wa yìn Ó o
- 5.Ẹ fi 'bùkún fún Ọlọ́run
- 6.Ìwọ tó lè wá la ó máa sìn títí
- 7.Èmi y'ó san ore o f'Ọlọ́run mi
- 8.Ẹ bá wá yin Olúwa, Alelúyà!
- 9.Ìyìn f'Ẹni Mímọ́
- 10.Àwọn ọmọdé ṣ'ẹkà wẹ́wẹ́ àt' imọ́pẹ s'ọ́nà
- 11.Ẹ̀mí Baba Alààyè
- 12.A ti mú mi l'aginjù ayé yìí ja
- 13.Fún wa ní 'lé Kristíánì
- 14.Nínú ìrìn àjò mi bẹ́ẹ̀ni mo ńkọrin
- 15.Ọlọ́run mi 'gbàtí mo f'ìyanu wò
- 16.Ọkàn wá kún f'ayọ̀ lónìí
- 17.Ó dámi lójú, mo ní Jésù
- 18.Mo dúró lórí ìlérí Krist' Ọba
- 19.Mo ti mb'ẹsẹ̀ rìn tipẹ́
- 20.Tọ́ asáko lọ, lọ f'ìfẹ́ rọ̀ wọ́n
- 21.Ṣá di orúkọ Jésù mú
- 22.Ẹ jẹ́ k'á kọrin tí y'ó dá wá láràyá
- 23.Ìgbàlà kíkún ní Ọlọ́run ṣe 'lérí
- 24.Ipè náà ńdùn l'ọ́tùnún àti l'ósì pé
- 25.N ó ha lọ ní ọwọ́ òfo?
- 26.Mo ntẹ̀síwájú l'ọ́nà náà
- 27.Ilé kan wà t'Ọlọ́run f'ìfẹ́ Rẹ̀ hàn
- 28.Ìgbà ayé wá á rọ gbẹdẹgbẹ́dẹ́
- 29.Ní àṣẹ t'ọba Bẹliṣásà pé f'àwọn 'jòyè rẹ̀
- 30.Mo ní láti ní O, Jésù
- 31.Gbọ́ bí Olúwa ti ńpè l'óhùn jẹ́jẹ́
- 32.Tẹ̀síwájú l'ọ́rọ̀ àkọ́mọ̀nà wá
- 33.Gbọ́ b'Ó ti wí 'Èmi kì y'ó gbàgbé rẹ'
- 34.'Gbàt' àláfíà b'ódò ńṣàn s'ọ́kàn mi
- 35.Olúwa ló pè wá, àwa náà sì ntẹ̀lé
- 36.Ìfẹ́ tí kò jẹ́ kí nsàkò
- 37.Mo ńsin Jésù t'ó jíǹde, ọ̀kanna ni lónìí
- 38.Ilé kan mbẹ t'ó dára jùlọ
- 39.Gbọ́ ìró ayọ̀ dídùn
- 40.Sọ ìtàn ti Jésù fún mi
- 41.Mo gbẹ́kẹ̀l' oníṣègùn, n'tór' ẹ̀ṣẹ̀ ni
- 42.Kò s'ọ́rẹ́ bíi Jésù onírẹ̀lẹ́
- 43.Ọkàn àt'ohùn mi
- 44.Olùgbàlà wá ọ̀wọ́n
- 45.Má jẹ́ k'ọ̀rọ̀ náà kọjá lọ
- 46.Wá ìwọ t'ẹrù ẹ̀ṣẹ̀ ńpa
- 47.Ẹ̀mí Mímọ́ dé l'ọjọ́ Pẹ́ńtíkọ́stì
- 48.Kristi Olùgbàlà wá n'nú ògo
- 49.Ojú mi ti rí ògo ìpadàbọ̀ Olúwa
- 50.Gbọ́ orin àwọn Ańgẹ́lì